2 Àwọn Ọba 25:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nebukadinésárì ọba Bábílónì yan Gẹdaláyà+ ọmọ Áhíkámù+ ọmọ Ṣáfánì+ ṣe olórí àwọn èèyàn tí ó fi sílẹ̀ ní ilẹ̀ Júdà.+ Jeremáyà 26:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Àmọ́ Áhíkámù+ ọmọ Ṣáfánì+ ran Jeremáyà lọ́wọ́, kí wọ́n má bàa fi í lé àwọn èèyàn náà lọ́wọ́ láti pa á.+
22 Nebukadinésárì ọba Bábílónì yan Gẹdaláyà+ ọmọ Áhíkámù+ ọmọ Ṣáfánì+ ṣe olórí àwọn èèyàn tí ó fi sílẹ̀ ní ilẹ̀ Júdà.+
24 Àmọ́ Áhíkámù+ ọmọ Ṣáfánì+ ran Jeremáyà lọ́wọ́, kí wọ́n má bàa fi í lé àwọn èèyàn náà lọ́wọ́ láti pa á.+