2 Àwọn Ọba 21:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ọmọ ọdún méjìlá (12) ni Mánásè+ nígbà tó jọba, ọdún márùndínlọ́gọ́ta (55) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+ Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Héfísíbà. 2 Àwọn Ọba 21:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó mọ àwọn pẹpẹ fún gbogbo ọmọ ogun ọ̀run+ sí àgbàlá méjì nínú ilé Jèhófà.+
21 Ọmọ ọdún méjìlá (12) ni Mánásè+ nígbà tó jọba, ọdún márùndínlọ́gọ́ta (55) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+ Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Héfísíbà.