-
Jeremáyà 52:12-14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Ní oṣù karùn-ún, ní ọjọ́ kẹwàá oṣù náà, ìyẹn, ní ọdún kọkàndínlógún Nebukadinésárì* ọba Bábílónì, Nebusarádánì olórí ẹ̀ṣọ́, tó jẹ́ ẹmẹ̀wà* ọba Bábílónì, wá sí Jerúsálẹ́mù.+ 13 Ó dáná sun ilé Jèhófà+ àti ilé* ọba pẹ̀lú gbogbo ilé tó wà ní Jerúsálẹ́mù; ó sì tún sun gbogbo ilé ńlá. 14 Gbogbo ògiri tó yí Jerúsálẹ́mù ká ni gbogbo àwọn ọmọ ogun Kálídíà tó wà pẹ̀lú olórí ẹ̀ṣọ́ wó lulẹ̀.+
-
-
Ìdárò 4:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Àwọn ọba ayé àti gbogbo àwọn tó ń gbé ilẹ̀ tó ń mú èso jáde kò gbà gbọ́
Pé elénìní àti ọ̀tá máa wọ àwọn ẹnubodè Jerúsálẹ́mù.+
-