Jeremáyà 34:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “‘Wò ó, màá pàṣẹ,’ ni Jèhófà wí, ‘màá sì mú wọn pa dà wá sí ìlú yìí, wọ́n á bá a jà, wọ́n á gbà á, wọ́n á sì dáná sun ún;+ màá sọ àwọn ìlú Júdà di ahoro tí ò ní sí ẹnì kankan tí á máa gbé ibẹ̀.’”+
22 “‘Wò ó, màá pàṣẹ,’ ni Jèhófà wí, ‘màá sì mú wọn pa dà wá sí ìlú yìí, wọ́n á bá a jà, wọ́n á gbà á, wọ́n á sì dáná sun ún;+ màá sọ àwọn ìlú Júdà di ahoro tí ò ní sí ẹnì kankan tí á máa gbé ibẹ̀.’”+