ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 11:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Àwọn èèyàn náà bá bẹ̀rẹ̀ sí í ráhùn gidigidi níwájú Jèhófà. Nígbà tí Jèhófà gbọ́, inú bí i gan-an, iná sì wá látọ̀dọ̀ Jèhófà, ó jó àwọn kan tó wà ní ìkángun ibùdó náà run.

  • Nọ́ńbà 16:35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 35 Iná sì wá látọ̀dọ̀ Jèhófà,+ ó jó igba ó lé àádọ́ta (250) ọkùnrin tó ń sun tùràrí+ run.

  • Lúùkù 9:54
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 54 Nígbà tí Jémíìsì àti Jòhánù,+ àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀, rí èyí, wọ́n sọ pé: “Olúwa, ṣé o fẹ́ ká pe iná sọ̀ kalẹ̀ láti ọ̀run, kó sì pa wọ́n run?”+

  • Júùdù 7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Lọ́nà kan náà, Sódómù àti Gòmórà àti àwọn ìlú tó yí wọn ká ṣe ìṣekúṣe* tó burú jáì, wọ́n ṣe ìfẹ́ tara tí kò bá ìwà ẹ̀dá mu.+ Ìdájọ́ ìparun* ayérayé tí wọ́n gbà jẹ́ àpẹẹrẹ láti kìlọ̀ fún wa.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́