Hébérù 11:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ìgbàgbọ́ mú ká ṣí Énọ́kù+ nípò pa dà kó má bàa rí ikú, a ò sì rí i níbì kankan torí pé Ọlọ́run ti ṣí i nípò pa dà;+ torí ká tó ṣí i nípò pa dà, ó rí ẹ̀rí pé ó ti ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run dáadáa.
5 Ìgbàgbọ́ mú ká ṣí Énọ́kù+ nípò pa dà kó má bàa rí ikú, a ò sì rí i níbì kankan torí pé Ọlọ́run ti ṣí i nípò pa dà;+ torí ká tó ṣí i nípò pa dà, ó rí ẹ̀rí pé ó ti ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run dáadáa.