1 Kíróníkà 15:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Nígbà náà, Dáfídì àti àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì pẹ̀lú àwọn olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún jọ ń rìn lọ tayọ̀tayọ̀+ láti gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà wá láti ilé Obedi-édómù.+
25 Nígbà náà, Dáfídì àti àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì pẹ̀lú àwọn olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún jọ ń rìn lọ tayọ̀tayọ̀+ láti gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà wá láti ilé Obedi-édómù.+