-
1 Sámúẹ́lì 7:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Yàtọ̀ síyẹn, àwọn ìlú tí àwọn Filísínì ti gbà lọ́wọ́ Ísírẹ́lì ni wọ́n dá pa dà fún Ísírẹ́lì, láti Ẹ́kírónì títí dé Gátì, Ísírẹ́lì sì gba ìpínlẹ̀ wọn pa dà lọ́wọ́ àwọn Filísínì.
Àlàáfíà sì tún wà láàárín Ísírẹ́lì àti àwọn Ámórì.+
-