2 Sámúẹ́lì 24:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nígbà tí áńgẹ́lì náà na ọwọ́ rẹ̀ sí Jerúsálẹ́mù láti pa á run, Jèhófà pèrò dà* lórí àjálù+ náà, ó sì sọ fún áńgẹ́lì tó ń pa àwọn èèyàn náà pé: “Ó tó gẹ́ẹ́! Gbé ọwọ́ rẹ wálẹ̀.” Áńgẹ́lì Jèhófà wà nítòsí ibi ìpakà Áráúnà+ ará Jébúsì.+ Sáàmù 103:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹ yin Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin áńgẹ́lì rẹ̀,+ tí ẹ jẹ́ alágbára ńlá,Tí ẹ̀ ń ṣe ohun tó sọ,+ tí ẹ sì ń fetí sí ohùn rẹ̀.*
16 Nígbà tí áńgẹ́lì náà na ọwọ́ rẹ̀ sí Jerúsálẹ́mù láti pa á run, Jèhófà pèrò dà* lórí àjálù+ náà, ó sì sọ fún áńgẹ́lì tó ń pa àwọn èèyàn náà pé: “Ó tó gẹ́ẹ́! Gbé ọwọ́ rẹ wálẹ̀.” Áńgẹ́lì Jèhófà wà nítòsí ibi ìpakà Áráúnà+ ará Jébúsì.+
20 Ẹ yin Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin áńgẹ́lì rẹ̀,+ tí ẹ jẹ́ alágbára ńlá,Tí ẹ̀ ń ṣe ohun tó sọ,+ tí ẹ sì ń fetí sí ohùn rẹ̀.*