1 Sámúẹ́lì 9:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 (Láyé àtijọ́ ní Ísírẹ́lì, ohun tí ẹni tó bá fẹ́ wá Ọlọ́run máa sọ nìyí: “Ẹ wá, ẹ jẹ́ ká lọ sọ́dọ̀ aríran.”+ Nítorí àwọn tí wọ́n ń pè ní aríran láyé àtijọ́ ni à ń pè ní wòlíì lóde òní.)
9 (Láyé àtijọ́ ní Ísírẹ́lì, ohun tí ẹni tó bá fẹ́ wá Ọlọ́run máa sọ nìyí: “Ẹ wá, ẹ jẹ́ ká lọ sọ́dọ̀ aríran.”+ Nítorí àwọn tí wọ́n ń pè ní aríran láyé àtijọ́ ni à ń pè ní wòlíì lóde òní.)