-
1 Kíróníkà 28:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Nígbà náà, Dáfídì kó gbogbo ìjòyè Ísírẹ́lì jọ sí Jerúsálẹ́mù, àwọn ni: àwọn ìjòyè ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan, àwọn olórí àwọn àwùjọ+ tó ń ṣe ìránṣẹ́ fún ọba, àwọn olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún àti àwọn olórí ọgọ́rọ̀ọ̀rún,+ àwọn olórí tó ń bójú tó gbogbo ohun ìní àti àwọn ẹran ọ̀sìn ọba+ àti ti àwọn ọmọ rẹ̀+ pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ ààfin àti àwọn ọkùnrin tó jẹ́ akíkanjú àti ọ̀jáfáfá.+
-