1 Àwọn Ọba 7:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ó fi bàbà ṣe kẹ̀kẹ́ ẹrù*+ mẹ́wàá. Gígùn kẹ̀kẹ́ ẹrù kọ̀ọ̀kan jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rin, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rin, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́ta. 1 Àwọn Ọba 7:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Ó ṣe bàsíà bàbà+ mẹ́wàá; ogójì (40) òṣùwọ̀n báàtì ni bàsíà kọ̀ọ̀kan ń gbà. Ìwọ̀n bàsíà kọ̀ọ̀kan jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rin.* Kẹ̀kẹ́ ẹrù mẹ́wẹ̀ẹ̀wá náà ní bàsíà kọ̀ọ̀kan lórí.
27 Ó fi bàbà ṣe kẹ̀kẹ́ ẹrù*+ mẹ́wàá. Gígùn kẹ̀kẹ́ ẹrù kọ̀ọ̀kan jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rin, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rin, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́ta.
38 Ó ṣe bàsíà bàbà+ mẹ́wàá; ogójì (40) òṣùwọ̀n báàtì ni bàsíà kọ̀ọ̀kan ń gbà. Ìwọ̀n bàsíà kọ̀ọ̀kan jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rin.* Kẹ̀kẹ́ ẹrù mẹ́wẹ̀ẹ̀wá náà ní bàsíà kọ̀ọ̀kan lórí.