-
2 Kíróníkà 32:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ọ̀pọ̀ èèyàn kóra jọ, wọ́n sì dí gbogbo ìsun omi pa àti odò tó ń ṣàn gba ilẹ̀ náà kọjá, wọ́n sọ pé: “A ò fẹ́ kí àwọn ọba Ásíríà rí omi lò nígbà tí wọ́n bá wá.”
-