Jẹ́nẹ́sísì 22:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Lẹ́yìn èyí, Ọlọ́run tòótọ́ dán Ábúráhámù wò,+ ó ní: “Ábúráhámù!” Ó fèsì pé: “Èmi nìyí!”