2 Àwọn Ọba 23:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó gbé òpó òrìṣà*+ jáde kúrò ní ilé Jèhófà lọ sí ẹ̀yìn Jerúsálẹ́mù, sí Àfonífojì Kídírónì, ó dáná sun ún+ ní Àfonífojì Kídírónì, ó lọ̀ ọ́ kúnná, ó sì fọ́n eruku rẹ̀ sórí sàréè àwọn èèyàn ìlú náà.+
6 Ó gbé òpó òrìṣà*+ jáde kúrò ní ilé Jèhófà lọ sí ẹ̀yìn Jerúsálẹ́mù, sí Àfonífojì Kídírónì, ó dáná sun ún+ ní Àfonífojì Kídírónì, ó lọ̀ ọ́ kúnná, ó sì fọ́n eruku rẹ̀ sórí sàréè àwọn èèyàn ìlú náà.+