2 Kíróníkà 29:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Lẹ́yìn ìyẹn, wọ́n lọ sọ́dọ̀ Ọba Hẹsikáyà, wọ́n sọ pé: “A ti fọ gbogbo ilé Jèhófà mọ́, pẹpẹ ẹbọ sísun+ pẹ̀lú gbogbo nǹkan èlò rẹ̀+ àti tábìlì búrẹ́dì onípele*+ pẹ̀lú gbogbo nǹkan èlò rẹ̀.
18 Lẹ́yìn ìyẹn, wọ́n lọ sọ́dọ̀ Ọba Hẹsikáyà, wọ́n sọ pé: “A ti fọ gbogbo ilé Jèhófà mọ́, pẹpẹ ẹbọ sísun+ pẹ̀lú gbogbo nǹkan èlò rẹ̀+ àti tábìlì búrẹ́dì onípele*+ pẹ̀lú gbogbo nǹkan èlò rẹ̀.