Jeremáyà 8:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ǹjẹ́ ojú tì wọ́n nítorí àwọn ohun ìríra tí wọ́n ṣe? Ojú kì í tì wọ́n! Àní wọn ò tiẹ̀ lójútì rárá!+ Torí náà, wọ́n á ṣubú láàárín àwọn tó ti ṣubú. Nígbà tí mo bá fìyà jẹ wọ́n, wọ́n á kọsẹ̀,’+ ni Jèhófà wí.
12 Ǹjẹ́ ojú tì wọ́n nítorí àwọn ohun ìríra tí wọ́n ṣe? Ojú kì í tì wọ́n! Àní wọn ò tiẹ̀ lójútì rárá!+ Torí náà, wọ́n á ṣubú láàárín àwọn tó ti ṣubú. Nígbà tí mo bá fìyà jẹ wọ́n, wọ́n á kọsẹ̀,’+ ni Jèhófà wí.