-
2 Kíróníkà 25:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Láti ìgbà tí Amasááyà ti pa dà lẹ́yìn Jèhófà ni wọ́n ti ń dìtẹ̀+ mọ́ ọn ní Jerúsálẹ́mù, ó sì sá lọ sí Lákíṣì, àmọ́ wọ́n rán àwọn kan tẹ̀ lé e lọ sí Lákíṣì, wọ́n sì pa á síbẹ̀.
-