2 Àwọn Ọba 21:25, 26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ní ti ìyókù ìtàn Ámọ́nì àti ohun tí ó ṣe, ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Júdà? 26 Nítorí náà, wọ́n sin ín sí sàréè rẹ̀ nínú ọgbà Úúsà,+ Jòsáyà+ ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.
25 Ní ti ìyókù ìtàn Ámọ́nì àti ohun tí ó ṣe, ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Júdà? 26 Nítorí náà, wọ́n sin ín sí sàréè rẹ̀ nínú ọgbà Úúsà,+ Jòsáyà+ ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.