2 Kíróníkà 33:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ẹni ọdún méjìlélógún (22) ni Ámọ́nì+ nígbà tó jọba, ọdún méjì ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+ 22 Ó ń ṣe ohun tó burú ní ojú Jèhófà, bí Mánásè bàbá rẹ̀ ti ṣe;+ Ámọ́nì rúbọ sí gbogbo àwọn ère gbígbẹ́ tí Mánásè bàbá rẹ̀ ṣe,+ ó sì ń sìn wọ́n.
21 Ẹni ọdún méjìlélógún (22) ni Ámọ́nì+ nígbà tó jọba, ọdún méjì ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+ 22 Ó ń ṣe ohun tó burú ní ojú Jèhófà, bí Mánásè bàbá rẹ̀ ti ṣe;+ Ámọ́nì rúbọ sí gbogbo àwọn ère gbígbẹ́ tí Mánásè bàbá rẹ̀ ṣe,+ ó sì ń sìn wọ́n.