ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 23:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Ọba wá pàṣẹ fún Hilikáyà+ àlùfáà àgbà àti àwọn àlùfáà yòókù àti àwọn aṣọ́nà pé kí wọ́n kó gbogbo nǹkan èlò tí àwọn èèyàn ṣe fún Báálì àti fún òpó òrìṣà*+ àti fún gbogbo ọmọ ogun ọ̀run jáde nínú tẹ́ńpìlì Jèhófà. Lẹ́yìn náà, ó dáná sun wọ́n ní ìta Jerúsálẹ́mù lórí ilẹ̀ onípele tó wà ní Kídírónì, ó sì kó eérú wọn lọ sí Bẹ́tẹ́lì.+

  • 2 Àwọn Ọba 23:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ó fọ́ àwọn ọwọ̀n òrìṣà, ó gé àwọn òpó òrìṣà*+ lulẹ̀, ó sì kó egungun àwọn èèyàn sí àyè wọn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́