-
2 Àwọn Ọba 23:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Nígbà tí Jòsáyà yíjú pa dà, tó sì rí àwọn sàréè tó wà lórí òkè, ó ní kí wọ́n kó àwọn egungun kúrò nínú àwọn sàréè náà, kí wọ́n sì sun wọ́n lórí pẹpẹ náà, kí ó lè sọ ọ́ di ibi tí kò ṣeé lò fún ìjọsìn, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Jèhófà tí èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ kéde, nígbà tó sọ tẹ́lẹ̀ pé àwọn nǹkan yìí máa ṣẹlẹ̀.+
-