-
2 Àwọn Ọba 17:41Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
41 Torí náà, àwọn orílẹ̀-èdè yìí ń bẹ̀rù Jèhófà,+ àmọ́ wọ́n tún ń sin àwọn ère gbígbẹ́ wọn. Àwọn ọmọ wọn àti àwọn ọmọ ọmọ wọn ń ṣe bí àwọn baba ńlá wọn ti ṣe, títí di òní yìí.
-