2 Àwọn Ọba 22:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Lọ bá Hilikáyà+ àlùfáà àgbà, ní kó gba gbogbo owó tí wọ́n mú wá sí ilé Jèhófà+ jọ, èyí tí àwọn aṣọ́nà gbà lọ́wọ́ àwọn èèyàn náà.+
4 “Lọ bá Hilikáyà+ àlùfáà àgbà, ní kó gba gbogbo owó tí wọ́n mú wá sí ilé Jèhófà+ jọ, èyí tí àwọn aṣọ́nà gbà lọ́wọ́ àwọn èèyàn náà.+