Ẹ́kísódù 12:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Mósè yára pe gbogbo àgbààgbà Ísírẹ́lì,+ ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ lọ mú àwọn ọmọ ẹran* fún ìdílé yín níkọ̀ọ̀kan, kí ẹ sì pa ẹran tí ẹ máa fi rúbọ nígbà Ìrékọjá.
21 Mósè yára pe gbogbo àgbààgbà Ísírẹ́lì,+ ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ lọ mú àwọn ọmọ ẹran* fún ìdílé yín níkọ̀ọ̀kan, kí ẹ sì pa ẹran tí ẹ máa fi rúbọ nígbà Ìrékọjá.