1 Kíróníkà 23:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 ẹgbẹ̀rún mẹ́rin (4,000) jẹ́ aṣọ́bodè,+ ẹgbẹ̀rún mẹ́rin (4,000) sì ń fi àwọn ohun ìkọrin yin+ Jèhófà, èyí tí Dáfídì sọ nípa wọn pé “mo ṣe wọ́n fún kíkọ orin ìyìn.”
5 ẹgbẹ̀rún mẹ́rin (4,000) jẹ́ aṣọ́bodè,+ ẹgbẹ̀rún mẹ́rin (4,000) sì ń fi àwọn ohun ìkọrin yin+ Jèhófà, èyí tí Dáfídì sọ nípa wọn pé “mo ṣe wọ́n fún kíkọ orin ìyìn.”