-
1 Kíróníkà 26:12, 13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Nínú àwọn àwùjọ tí a pín àwọn aṣọ́bodè yìí sí, bí àwọn olórí ṣe ní iṣẹ́ ni àwọn arákùnrin wọn náà ṣe ní iṣẹ́, láti máa ṣe ìránṣẹ́ ní ilé Jèhófà. 13 Torí náà, wọ́n ṣẹ́ kèké+ fún ẹni kékeré bí wọ́n ṣe ṣẹ́ ẹ fún ẹni ńlá ní agbo ilé bàbá wọn, fún ẹnubodè kọ̀ọ̀kan.
-