2 Àwọn Ọba 23:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ọba wá pàṣẹ fún gbogbo àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ ṣe Ìrékọjá+ sí Jèhófà Ọlọ́run yín gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé májẹ̀mú yìí.”+
21 Ọba wá pàṣẹ fún gbogbo àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ ṣe Ìrékọjá+ sí Jèhófà Ọlọ́run yín gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé májẹ̀mú yìí.”+