Jeremáyà 46:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Sí Íjíbítì,+ nípa àwọn ọmọ ogun Fáráò Nékò + ọba Íjíbítì, tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ odò Yúfírétì, ẹni tí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì ṣẹ́gun ní Kákémíṣì, ní ọdún kẹrin Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà:
2 Sí Íjíbítì,+ nípa àwọn ọmọ ogun Fáráò Nékò + ọba Íjíbítì, tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ odò Yúfírétì, ẹni tí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì ṣẹ́gun ní Kákémíṣì, ní ọdún kẹrin Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà: