-
1 Àwọn Ọba 22:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Ọba Ísírẹ́lì sì sọ fún Jèhóṣáfátì pé: “Màá para dà, màá sì lọ sójú ogun, ṣùgbọ́n ní tìrẹ, wọ ẹ̀wù oyè rẹ.” Torí náà, ọba Ísírẹ́lì para dà,+ ó sì bọ́ sójú ogun.
-