Àwọn Onídàájọ́ 1:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Mánásè ò gba Bẹti-ṣéánì àti àwọn àrọko rẹ̀,* Táánákì+ àti àwọn àrọko rẹ̀, àwọn tó ń gbé Dórì àti àwọn àrọko rẹ̀, àwọn tó ń gbé Íbíléámù àti àwọn àrọko+ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn tó ń gbé Mẹ́gídò àti àwọn àrọko rẹ̀. Àwọn ọmọ Kénáánì ṣì ń gbé ní ilẹ̀ yìí. Àwọn Onídàájọ́ 5:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àwọn ọba wá, wọ́n sì jà;Àwọn ọba Kénáánì wá jà +Ní Táánákì, létí omi Mẹ́gídò.+ Wọn ò kó+ fàdákà kankan lójú ogun. Sekaráyà 12:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n á pohùn réré ẹkún gan-an ní Jerúsálẹ́mù, bí ẹkún tí wọ́n sun ní Hadadirímónì ní Pẹ̀tẹ́lẹ̀ Mẹ́gídò.+ Ìfihàn 16:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Wọ́n sì kó wọn jọ sí ibi tí wọ́n ń pè ní Amágẹ́dọ́nì*+ lédè Hébérù.
27 Mánásè ò gba Bẹti-ṣéánì àti àwọn àrọko rẹ̀,* Táánákì+ àti àwọn àrọko rẹ̀, àwọn tó ń gbé Dórì àti àwọn àrọko rẹ̀, àwọn tó ń gbé Íbíléámù àti àwọn àrọko+ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn tó ń gbé Mẹ́gídò àti àwọn àrọko rẹ̀. Àwọn ọmọ Kénáánì ṣì ń gbé ní ilẹ̀ yìí.
19 Àwọn ọba wá, wọ́n sì jà;Àwọn ọba Kénáánì wá jà +Ní Táánákì, létí omi Mẹ́gídò.+ Wọn ò kó+ fàdákà kankan lójú ogun.
11 Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n á pohùn réré ẹkún gan-an ní Jerúsálẹ́mù, bí ẹkún tí wọ́n sun ní Hadadirímónì ní Pẹ̀tẹ́lẹ̀ Mẹ́gídò.+