-
Jeremáyà 9:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí,
‘Ẹ fi òye hùwà.
Ẹ pe àwọn obìnrin tó ń kọ orin arò,*+
Kí ẹ sì ránṣẹ́ pe àwọn obìnrin tó já fáfá,
-
Jeremáyà 9:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ẹ̀yin obìnrin, ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà.
Ẹ jẹ́ kí etí yín gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀.
-
-
-