2 Àwọn Ọba 24:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Nígbà ayé Jèhóákímù, Nebukadinésárì+ ọba Bábílónì wá gbéjà kò ó, Jèhóákímù sì fi ọdún mẹ́ta ṣe ìránṣẹ́ fún un. Àmọ́, ó yí pa dà, ó sì ṣọ̀tẹ̀. 2 Àwọn Ọba 25:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ní ọdún kẹsàn-án ìjọba Sedekáyà, ní oṣù kẹwàá, ní ọjọ́ kẹwàá oṣù náà, Nebukadinésárì+ ọba Bábílónì dé pẹ̀lú gbogbo ọmọ ogun rẹ̀ láti gbéjà ko Jerúsálẹ́mù.+ Ó dó tì í, ó mọ òkìtì yí i ká,+ Jeremáyà 25:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà gbọ́ nípa gbogbo àwọn èèyàn Júdà ní ọdún kẹrin Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà, ìyẹn ní ọdún kìíní Nebukadinésárì* ọba Bábílónì.
24 Nígbà ayé Jèhóákímù, Nebukadinésárì+ ọba Bábílónì wá gbéjà kò ó, Jèhóákímù sì fi ọdún mẹ́ta ṣe ìránṣẹ́ fún un. Àmọ́, ó yí pa dà, ó sì ṣọ̀tẹ̀.
25 Ní ọdún kẹsàn-án ìjọba Sedekáyà, ní oṣù kẹwàá, ní ọjọ́ kẹwàá oṣù náà, Nebukadinésárì+ ọba Bábílónì dé pẹ̀lú gbogbo ọmọ ogun rẹ̀ láti gbéjà ko Jerúsálẹ́mù.+ Ó dó tì í, ó mọ òkìtì yí i ká,+
25 Ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà gbọ́ nípa gbogbo àwọn èèyàn Júdà ní ọdún kẹrin Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà, ìyẹn ní ọdún kìíní Nebukadinésárì* ọba Bábílónì.