2 Àwọn Ọba 24:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní ti ìyókù ìtàn Jèhóákímù àti gbogbo ohun tí ó ṣe, ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Júdà?+ 6 Níkẹyìn, Jèhóákímù sinmi pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀;+ Jèhóákínì ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.
5 Ní ti ìyókù ìtàn Jèhóákímù àti gbogbo ohun tí ó ṣe, ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Júdà?+ 6 Níkẹyìn, Jèhóákímù sinmi pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀;+ Jèhóákínì ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.