-
Ìsíkíẹ́lì 9:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Lẹ́yìn náà, ó sọ fún wọn pé: “Ẹ sọ ilé náà di ẹlẹ́gbin, kí ẹ sì fi òkú èèyàn kún inú àwọn àgbàlá.+ Ẹ lọ!” Ni wọ́n bá lọ, wọ́n sì pa àwọn èèyàn ní ìlú náà.
-