Ẹ́kísódù 34:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Kí ìwọ fúnra rẹ gbẹ́ wàláà òkúta méjì, irú ti àkọ́kọ́,+ màá sì kọ àwọn ọ̀rọ̀ tó wà lórí àwọn wàláà àkọ́kọ́+ tí o fọ́ túútúú+ sára rẹ̀. Ẹ́kísódù 40:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Lẹ́yìn náà, ó mú Ẹ̀rí,+ ó sì fi sínú Àpótí náà.+ Ó ki àwọn ọ̀pá+ sí ẹ̀gbẹ́ Àpótí náà, ó sì fi ìbòrí+ bo Àpótí náà.+
34 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Kí ìwọ fúnra rẹ gbẹ́ wàláà òkúta méjì, irú ti àkọ́kọ́,+ màá sì kọ àwọn ọ̀rọ̀ tó wà lórí àwọn wàláà àkọ́kọ́+ tí o fọ́ túútúú+ sára rẹ̀.
20 Lẹ́yìn náà, ó mú Ẹ̀rí,+ ó sì fi sínú Àpótí náà.+ Ó ki àwọn ọ̀pá+ sí ẹ̀gbẹ́ Àpótí náà, ó sì fi ìbòrí+ bo Àpótí náà.+