ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kíróníkà 16:41
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 41 Àwọn tó wà pẹ̀lú wọn ni Hémánì àti Jédútúnì+ pẹ̀lú ìyókù àwọn ọkùnrin tí a fi orúkọ yàn láti máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà,+ nítorí “ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé”;+

  • 1 Kíróníkà 25:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Síwájú sí i, Dáfídì àti àwọn olórí àwùjọ àwọn tó ń ṣiṣẹ́ ìsìn ya àwọn kan lára àwọn ọmọ Ásáfù, Hémánì àti Jédútúnì+ sọ́tọ̀ láti máa fi háàpù, àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín+ àti síńbálì*+ sọ tẹ́lẹ̀. Orúkọ àwọn tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn yìí ni,

  • 1 Kíróníkà 25:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Gbogbo wọn wà lábẹ́ ìdarí bàbá wọn láti máa kọrin ní ilé Jèhófà pẹ̀lú síńbálì, àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti háàpù+ fún iṣẹ́ ìsìn ilé Ọlọ́run tòótọ́.

      Àwọn tó wà lábẹ́ àṣẹ ọba ni Ásáfù, Jédútúnì àti Hémánì.

  • 1 Kíróníkà 25:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Látinú Jédútúnì,+ àwọn ọmọ Jédútúnì ni: Gẹdaláyà, Séérì, Jeṣáyà, Ṣíméì, Haṣabáyà àti Matitáyà,+ wọ́n jẹ́ mẹ́fà lábẹ́ ìdarí bàbá wọn Jédútúnì, ẹni tó ń fi háàpù sọ tẹ́lẹ̀, láti máa dúpẹ́ àti láti máa yin Jèhófà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́