-
1 Àwọn Ọba 8:54Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
54 Gbàrà tí Sólómọ́nì parí gbogbo àdúrà yìí sí Jèhófà àti ẹ̀bẹ̀ rẹ̀ fún ojú rere, ó dìde kúrò níwájú pẹpẹ Jèhófà, níbi tí ó kúnlẹ̀ sí, tí ó sì tẹ́ ọwọ́ rẹ̀ sí ọ̀run.+
-