-
Hágáì 2:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 mo fi ooru tó ń jó nǹkan gbẹ àti èbíbu+ àti yìnyín kọ lù yín, àní gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ yín, àmọ́ ẹnì kankan lára yín ò pa dà sọ́dọ̀ mi,’ ni Jèhófà wí.
-