2 Kíróníkà 9:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Sólómọ́nì ní ẹgbẹ̀rún mẹ́rin (4,000) ilé ẹṣin fún àwọn ẹṣin àti kẹ̀kẹ́ ẹṣin rẹ̀, ó sì ní ẹgbẹ̀rún méjìlá (12,000) ẹṣin,*+ ó kó wọn sí àwọn ìlú kẹ̀kẹ́ ẹṣin àti sí tòsí ọba ní Jerúsálẹ́mù.+
25 Sólómọ́nì ní ẹgbẹ̀rún mẹ́rin (4,000) ilé ẹṣin fún àwọn ẹṣin àti kẹ̀kẹ́ ẹṣin rẹ̀, ó sì ní ẹgbẹ̀rún méjìlá (12,000) ẹṣin,*+ ó kó wọn sí àwọn ìlú kẹ̀kẹ́ ẹṣin àti sí tòsí ọba ní Jerúsálẹ́mù.+