Ẹ́kísódù 40:34, 35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ìkùukùu* sì bẹ̀rẹ̀ sí í bo àgọ́ ìpàdé, ògo Jèhófà sì kún inú àgọ́ ìjọsìn náà.+ 35 Mósè ò lè wọnú àgọ́ ìpàdé torí pé ìkùukùu ò kúrò lórí àgọ́ náà, ògo Jèhófà sì kún inú àgọ́ ìjọsìn náà.+
34 Ìkùukùu* sì bẹ̀rẹ̀ sí í bo àgọ́ ìpàdé, ògo Jèhófà sì kún inú àgọ́ ìjọsìn náà.+ 35 Mósè ò lè wọnú àgọ́ ìpàdé torí pé ìkùukùu ò kúrò lórí àgọ́ náà, ògo Jèhófà sì kún inú àgọ́ ìjọsìn náà.+