Àìsáyà 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí kún ilẹ̀ wọn.+ Wọ́n ń forí balẹ̀ fún iṣẹ́ ọwọ́ ara wọn,Fún ohun tí wọ́n fi ìka ara wọn ṣe. Jeremáyà 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ǹjẹ́ orílẹ̀-èdè kan ti fi ohun tí kì í ṣe ọlọ́run rọ́pò ọlọ́run rẹ̀ rí? Ṣùgbọ́n àwọn èèyàn mi ti fi ohun tí kò wúlò rọ́pò ògo mi.+
8 Àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí kún ilẹ̀ wọn.+ Wọ́n ń forí balẹ̀ fún iṣẹ́ ọwọ́ ara wọn,Fún ohun tí wọ́n fi ìka ara wọn ṣe.
11 Ǹjẹ́ orílẹ̀-èdè kan ti fi ohun tí kì í ṣe ọlọ́run rọ́pò ọlọ́run rẹ̀ rí? Ṣùgbọ́n àwọn èèyàn mi ti fi ohun tí kò wúlò rọ́pò ògo mi.+