1 Àwọn Ọba 5:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nígbà tí Hírámù ọba Tírè+ gbọ́ pé a ti fòróró yan Sólómọ́nì láti jọba ní ipò bàbá rẹ̀, ó rán àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ sí Sólómọ́nì, nítorí tipẹ́tipẹ́ ni Hírámù ti jẹ́ ọ̀rẹ́* Dáfídì.+
5 Nígbà tí Hírámù ọba Tírè+ gbọ́ pé a ti fòróró yan Sólómọ́nì láti jọba ní ipò bàbá rẹ̀, ó rán àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ sí Sólómọ́nì, nítorí tipẹ́tipẹ́ ni Hírámù ti jẹ́ ọ̀rẹ́* Dáfídì.+