1 Kíróníkà 16:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Torí náà, wọ́n gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ wọlé, wọ́n sì gbé e kalẹ̀ sí àyè rẹ̀ nínú àgọ́ tí Dáfídì pa fún un;+ wọ́n mú àwọn ẹbọ sísun àti àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀ wá síwájú Ọlọ́run tòótọ́.+
16 Torí náà, wọ́n gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ wọlé, wọ́n sì gbé e kalẹ̀ sí àyè rẹ̀ nínú àgọ́ tí Dáfídì pa fún un;+ wọ́n mú àwọn ẹbọ sísun àti àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀ wá síwájú Ọlọ́run tòótọ́.+