Émọ́sì 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ọ̀rọ̀ Émọ́sì,* ọ̀kan lára àwọn tó ń sin àgùntàn láti Tékóà,+ èyí tó gbọ́ nínú ìran nípa Ísírẹ́lì nígbà ayé Ùsáyà+ ọba Júdà àti nígbà ayé Jèróbóámù+ ọmọ Jóáṣì,+ ọba Ísírẹ́lì, ní ọdún méjì ṣáájú ìmìtìtì ilẹ̀ tó wáyé.+
1 Ọ̀rọ̀ Émọ́sì,* ọ̀kan lára àwọn tó ń sin àgùntàn láti Tékóà,+ èyí tó gbọ́ nínú ìran nípa Ísírẹ́lì nígbà ayé Ùsáyà+ ọba Júdà àti nígbà ayé Jèróbóámù+ ọmọ Jóáṣì,+ ọba Ísírẹ́lì, ní ọdún méjì ṣáájú ìmìtìtì ilẹ̀ tó wáyé.+