1 Àwọn Ọba 11:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Torí náà, Sólómọ́nì wá ọ̀nà láti pa Jèróbóámù, àmọ́ Jèróbóámù sá lọ sí Íjíbítì, lọ́dọ̀ Ṣíṣákì+ ọba Íjíbítì,+ ó sì ń gbé ní Íjíbítì títí Sólómọ́nì fi kú. 1 Àwọn Ọba 14:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ní ọdún karùn-ún Ọba Rèhóbóámù, Ṣíṣákì+ ọba Íjíbítì wá gbéjà ko Jerúsálẹ́mù.+
40 Torí náà, Sólómọ́nì wá ọ̀nà láti pa Jèróbóámù, àmọ́ Jèróbóámù sá lọ sí Íjíbítì, lọ́dọ̀ Ṣíṣákì+ ọba Íjíbítì,+ ó sì ń gbé ní Íjíbítì títí Sólómọ́nì fi kú.