2 Kíróníkà 9:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ní ti ìyókù ìtàn Sólómọ́nì,+ láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin, ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ọ̀rọ̀ wòlíì Nátánì,+ nínú àsọtẹ́lẹ̀ Áhíjà+ ọmọ Ṣílò àti nínú àkọsílẹ̀ àwọn ìran Ídò+ aríran tó sọ nípa Jèróbóámù+ ọmọ Nébátì? 2 Kíróníkà 13:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ìyókù ìtàn Ábíjà, àwọn ohun tó ṣe àti àwọn ọ̀rọ̀ rẹ̀ wà lákọsílẹ̀ nínú àwọn ìwé* wòlíì Ídò.+
29 Ní ti ìyókù ìtàn Sólómọ́nì,+ láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin, ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ọ̀rọ̀ wòlíì Nátánì,+ nínú àsọtẹ́lẹ̀ Áhíjà+ ọmọ Ṣílò àti nínú àkọsílẹ̀ àwọn ìran Ídò+ aríran tó sọ nípa Jèróbóámù+ ọmọ Nébátì?