Sáàmù 89:28, 29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Èmi yóò máa fi ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ hàn sí i títí láé,+Májẹ̀mú tí mo bá a dá kò sì ní yẹ̀ láé.+ 29 Màá fìdí àwọn ọmọ* rẹ̀ múlẹ̀ títí láé,Màá sì mú kí ìtẹ́ rẹ̀ wà títí lọ bí ọ̀run.+
28 Èmi yóò máa fi ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ hàn sí i títí láé,+Májẹ̀mú tí mo bá a dá kò sì ní yẹ̀ láé.+ 29 Màá fìdí àwọn ọmọ* rẹ̀ múlẹ̀ títí láé,Màá sì mú kí ìtẹ́ rẹ̀ wà títí lọ bí ọ̀run.+