2 Kíróníkà 10:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Gbàrà tí Jèróbóámù+ ọmọ Nébátì gbọ́ (ó ṣì wà ní Íjíbítì torí ó ti sá lọ nítorí Ọba Sólómọ́nì),+ Jèróbóámù pa dà wá láti Íjíbítì.
2 Gbàrà tí Jèróbóámù+ ọmọ Nébátì gbọ́ (ó ṣì wà ní Íjíbítì torí ó ti sá lọ nítorí Ọba Sólómọ́nì),+ Jèróbóámù pa dà wá láti Íjíbítì.