-
1 Àwọn Ọba 12:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Ó kọ́ àwọn ilé ìjọsìn sórí àwọn ibi gíga, ó sì yan àwọn àlùfáà látinú gbogbo àwọn èèyàn náà, àwọn tí kì í ṣe ọmọ Léfì.+
-
-
1 Àwọn Ọba 12:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Ó bẹ̀rẹ̀ sí í mú àwọn ọrẹ wá sórí pẹpẹ tó ṣe ní Bẹ́tẹ́lì ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún ní oṣù kẹjọ, ní oṣù tí òun fúnra rẹ̀ yàn; ó dá àjọyọ̀ kan sílẹ̀ fún àwọn èèyàn Ísírẹ́lì, ó sì lọ sórí pẹpẹ láti mú ọrẹ àti ẹbọ rú èéfín.
-